FOREIGN

Baba Ijesha dèrò àtìmọ́lé lórí ẹ̀sùn pé ó bá ọmọ ọdún mẹ̀rìnlá lòpọ̀ nílùú Eko
Read Time:1 Minute, 7 Second

Baba Ijesha dèrò àtìmọ́lé lórí ẹ̀sùn pé ó bá ọmọ ọdún mẹ̀rìnlá lòpọ̀ nílùú Eko

0 0

Baba Ijesha dèrò àtìmọ́lé lórí ẹ̀sùn pé ó bá ọmọ ọdún mẹ̀rìnlá lòpọ̀ nílùú Eko

Baba Ijesha

Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko ti kede pe awọn ti fi ṣikun ofin mu gbajugbaja oṣere tiata Yoruba, Olanrewaju James, ti ọpọ awọn ololufẹ rẹ mọ si Baba Ijesha.

Ninu atẹjade kan ti alukoro ileeṣẹ naa, Muyiwa Adejobi fi sọwọ si BBC Yoruba, o ni awọn mu Baba Ijesha lori ẹsun pe o ba ọmọ ọdun mẹrinla ni ibalopọ.

Atẹjade naa ni “Ileeṣẹ ọloọpaa ipinlẹ Eko ti fi ṣikun ofin mu Olanrewaju James, ẹni ọdun mejidinlaadọta, ti awọn eeyan mọ si Baba Ijesha lori ẹsun pe o ba ọmọ ọdun mẹrinla lopọ.”

Obinrin kan ti orukọ rẹ n jẹ Princess Adekola Adekanya lo fi ọrọ naa to ile iṣẹ wa to wa ni Sabo leti lọjọ kọkandinlogin, oṣu Kẹrin, ọdun 2021.”

Adejobi tẹsiwaju ninu atẹjade naa pe iwadii ti awọn ṣe fi han pe afurasi naa ti n ba ọmọ ọhun ni ibalopọ lati akoko to wa ni ọmọ ọdun meje.

Àkọlé fídíò, aaaaaaaaaaaaaaa

O ni “Afurasi naa jẹwọ pe lootọ ni oun ṣe ẹṣun ti wọn fi kan oun.”

Adejọbi fi kun pe ẹrọ ayaworan CCTV to wa ninu ile ti iṣẹlẹ naa ti waye tun ka afurasi naa silẹ.

Similar Posts:

About Post Author

Happy
Happy
0 %
Sad
Sad
0 %
Excited
Excited
0 %
Sleepy
Sleepy
0 %
Angry
Angry
0 %
Surprise
Surprise
0 %

Average Rating

5 Star
0%
4 Star
0%
3 Star
0%
2 Star
0%
1 Star
0%

Leave a Reply

Your email address will not be published.

%d bloggers like this: